Anígunpúpọ̀ ninu Jeometri je irisi aworan pepe ti o je pipade pipade pelu ila tabi ona ayipo, to ni itelentele tolopin awon ajapo ila gboro (eyun, pelu closed polygonal chain). Awon ajapo ila wonyi je pipe ni egbe tabi eti, be sini ojuami ti awon egbe mejeji ti pade ni an pe ni sonso tabi koro anigunpupo na. Inu re ni an pe ni ara.

Awon orisirisi anigunpupo



  翻译: