Jump to content

Ẹ́gíptì Ayéijọ́un

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìtàn ilẹ̀ Ẹ́gíptì


Àyọkà yìí jẹ́ ìkan nínú àwọn àyọkà ẹlẹ́sẹẹsẹ
Ẹ́gíptì Ayéijọ́un
Ẹ́gíptì Aṣíwájú Ìran-ọba
Ẹ́gíptì Ìran-ọba Àkọ́kọ́
Ìgbà Ìran-ọba Ìbẹ̀rẹ̀
Ilẹ̀ọba Àtijọ́
Ìgbà Àpínyà Àkọ́kọ́
Ilẹ̀ọba Àrin
Ìgbà Àpínyà Kejì
Ilẹ̀ọba Tuntun
Ìgbà Àpínyà Kẹta
Ìgbà Àkọ́kọ́ Akẹmẹ́nídì
Ìgbà Ìgbẹ̀yìn
Ìgbà Kejì Akẹmẹ́nídì
Ìgbà Ptolemy
Alẹksándà Ẹnínlá
Ptolemaic Egypt
Roman & Byzantine Egypt
Christian Egypt
Byzantine Egypt
Sassanid Occupation
Muslim Egypt
Fatimid Egypt
Ayyubid Egypt
Mamluk Egypt
Ottoman Egypt
Modern Egypt
French Campaign
Muhammad Ali Dynasty
Khedivate of Egypt
Sultanate of Egypt
Kingdom of Egypt
Republic
Fall of Mubarak Government
{Àdàkọ:Data99

Èbúté Ẹ́gíptì
Àwọn Ìran-ọba Ẹ́gíptì Ayéijọ́un
Ẹ́gíptì Aṣíwájú Ìran-ọba
Ìgbà Ìran-ọba Àkọ́kọ́
Ìgbà Ìran-ọba Ìbẹ̀rẹ̀
Ilẹ̀ọba Àtijọ́
Ìgbà Apínníyà Àkọ́kọ́
Middle Kingdom
Ìgbà Apínníyà Kejì
Ilẹ̀ọba Tuntun
Ìgbà Apínníyà Kẹta
First Persian Period
Late Period
Second Persian Period
Ptolemaic Dynasty
pyramids ti Giza
(c. 3150 BC - 30 BC)

Ẹ́gíptì Ayéijọ́un ni asailaju ayeijoun ti apailaorun Ariwa Afrika, to wo jo si isale Odo Nile nibi ti orile-ede ayeodeoni Egypt wa. Asailaju ti ara Egypti gbajo ni bi odun 3150 SK (gegebi Iseoroasiko apejose ti ara Egypti )[1] pelu isodokan oselu Apa Oke ati Apa Isale Egypti labe farao akoko.[2] Itan Egypti ayeijoun sele bi eseese awon Ileoba, ti won je pinpinniya pelu awon igba aitoro ti won unje Igba Apinniya. Ileoba Atijo ti Igba Ibere Amobaba, Ileoba Arin ti Igba Arin Amobaba ati Ileoba Tuntun ti Igba Opin Amobaba. Egypti de ogo agbara re nigba Ileoba Tuntun, ni igba Ramesi, leyin eyi ni obere si ni bo si igba irele diedie. Egypt je sisegun latowo awon alagbara okere ni titelentele. Leyin iku Aleksanda Eninla, ikan ninu awon ogagun re to unje Ptolemy Soter, so ara re di ajoba tuntun Egypt. Iran-oba Ptolemi yi joba lori Egypt titi de odun 30 SK, nigba to bo sowo Ile Romu to si di igberiko Romu.[3]

Ijasirere asailaju Egipti ayeijoun je be nitori agbara re lati le gbe pelu awon isele Ifonofoji Odo Nilo. Agbara asotele ati ikojanu ibomirin ile olora inu afonifoji fa opo eso ogbin wa, eyi lo si mu idagbasoke awujo ati asa wa. Pelu opo ohun amulo o se ese fun ijoba lati segbowo imulo awon alumoni to wa ni afonifoji Nilo ati awon agbegbe ashale to yika, atetebere idagbasoke sistemu ikoole fun ra ara won, igbajo ikole akojopo ati awon iseowo iseagbe, idunadura pelu awon agbegbe ayika, ati ise ologun to fe segun awon ota okere to si le fi agbara Egypti han. Lati sakoso awon agbese wonyi ni awon akowe, olori esin, ati awo aseamojuto labe ijanu Farao, eni to ridaju pe awon eniyan ara Egipti wa lokan labe sistemu awon igbagbo esin.[4][5]

Ninu awon opo oriire awon ara Egipti ayeijoun ni okuta fifo, ile wiwon ati awon ona ikole to fa kiko awon piramidi gbangba, tempili, ati obeliski; sistemu mathimatiki, sistemu iwosan to sise ati to se e mulo, awon sistemu ibomirin ati ona ida iseagbe, awon oko-ojuomi akoko, amo fiyansi Egypti ati iseoroiseona digi (gilasi), iru isemookomooka tuntun, ati adehun alafia atetejulo ti a mo.[6] Egypt left a lasting legacy. Its art and architecture were widely copied, and its antiquities carried off to far corners of the world. Its monumental ruins have inspired the imaginations of travellers and writers for centuries. A new-found respect for antiquities and excavations in the early modern period led to the scientific investigation of Egyptian civilization and a greater appreciation of its cultural legacy.[7]

Ìgbà aṣíwájú ìran-ọba

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

ṣaaju ki Oba (ọdun 3150–2686)

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ijọba atijọ (2686–2181)

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Laarin (2134–1690)

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ijọba Tuntun (1549–1069)

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nigbamii (653–332)

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Πτολεμαῖος Σωτήρ (332–30)

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ilẹ̀ọbalúayé Rómù Apáìwọ̀orùn (30 – 641)

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


  1. "Chronology". Digital Egypt for Universities, University College London. Retrieved 25 March 2008. 
  2. Dodson (2004) p. 46
  3. Clayton (1994) p. 217
  4. James (2005) p. 8
  5. Manuelian (1998) pp. 6–7
  6. Clayton (1994) p. 153
  7. James (2005) p. 84
  翻译: